Skip Navigation

Cine

Corazón y sistema circulatorio


 

3 semanas

Compre ahoraDe La biología del desarrollo prenatal

Guión: Bi ẹjẹ akọkọ ba ti de inu apo ẹyin, iho ara ti ẹjẹ ngba yio farahan kaakiri lara ọmọ inu oyun naa, bẹẹ si ni ọkan, eyiti o ri rogodo, yio farahan bakanna.

O fẹrẹ jẹ lẹsẹkanna ni ọkan ti ndagbasoke ni kiakia yi yio sẹpo sori ara rẹ, bẹẹ si ni apo ọtọọtọ yio maa waye laarin ọkan naa.

Ọkan naa yio bẹrẹ sii mi lati ọsẹ kẹta ati ọjọ kan lẹhin idapọ ẹyin ọkọ ati aya.

Ẹya ara ti ngbe ẹjẹ kiri gbogbo ara jẹ ẹya ara akọkọ, tabi akojọpọ awọn ẹya ara ti o jọ ara wọn lati bẹrẹ sii S̩iS̩ẹ.

Todas las edades en referencia a la fecundación, no al último período menstrual.
 <  Anterior    Ver fotos instantáneas    Siguiente  > 
Corazón y sistema circulatorio
Corazón y sistema circulatorio
El plegamiento del embrión
El plegamiento del embrión
El plegamiento del embrión
El plegamiento del embrión
Desarrollo del corazón
Desarrollo del corazón
El embrión y el saco vitelino
El embrión y el saco vitelino
Desarrollo embrionario
Desarrollo embrionario
Previous Set Previous Picture Next Set Next Picture