CineResponde al sonido |
| Compre ahoraDe La biología del desarrollo prenatal |
|
Guión: OS̩U MARUN Ni ogun ọsẹ, apa kan ninu iho eti, eyiti o jẹ ẹya ara ti igbọran, yio ti tobi to ti agbalagba ninu iho eti ti o ti dagbasoke tan naa. Lati igba yi lọ, ọmọ inu oyun yio maa fesi si oriS̩iriS̩i ariwo. |
|
Todas las edades en referencia a la fecundación, no al último período menstrual.
Un mes = 4 semanas.
|
| < Anterior | Ver fotos instantáneas | Siguiente > |
|
|




