CineEl reflejo perioral |
Compre ahoraDe La biología del desarrollo prenatal |
Guión: Yatọ si bi o ti ma nS̩e tẹlẹ ri, bi a ba fọwọkan ẹnu ọmọ inu oyun yi, yio yirapada si ọkankan ibiti a ti fọwọkan-an, yio si la ẹnu rẹ. Iru ifesi bayi ni a npe ni “rutini rifulẹkisi” o si ma ntẹsiwaju lẹhin ti ọmọ naa ba d’aye tan, ninu eyiti i ma ran ọmọ lọwọ lati wa ibiti ori-ọmu iya rẹ wa, nigbati o ba fẹ mu ọmu. |
Todas las edades en referencia a la fecundación, no al último período menstrual.
Un mes = 4 semanas.
|
< Anterior | Ver fotos instantáneas | Siguiente > |