CineEvacuación intestinal |
Compre ahoraDe La biología del desarrollo prenatal |
Guión: Igbẹ yiya yio bẹrẹ lati bi ọsẹ kejila, yio si tẹsiwaju fun bi ọsẹ mẹfa sii. Ohun akọkọ tii ma jade lati idi ọmọ inu oyun ati ọmọ ti a S̩ẹS̩ẹ bi ni a npe ni mẹkoniọmu. Ninu rẹ ni a ti le ri awọn ohun ti nmu ounjẹ da, ounjẹ tii mu ni dagbasoke, ati awọn ẹyin keekeke ti ko wulo mọ, eyiti o jade lati inu ẹya ara ti ngbe ounjẹ kaakiri ara. |
Todas las edades en referencia a la fecundación, no al último período menstrual.
Un mes = 4 semanas.
|
< Anterior | Ver fotos instantáneas | Siguiente > |