CineMovimiento y sensación |
| Compre ahoraDe La biología del desarrollo prenatal |
|
Guión: Ọmọ inu oyun naa le di nkan mu, o le mi ori rẹ siwaju ati sẹhin, o le la ẹnu rẹ, o le gbe ahọn rẹ, o le poS̩e, osi le na. Isan-ara ti o wa ni oju, atẹlẹwọ, ati atẹlẹsẹ ma nmọ ọ lara bi a ba fi ọwọ kan wọn. “Bi a ba rọra fi ọwọ kan gigise,” ọmọ inu oyun yio rọ ibadi rẹ ati orunkun rẹ yio si lẹ ọmọ-ika ẹsẹ rẹ pọ |
|
Todas las edades en referencia a la fecundación, no al último período menstrual.
|
| < Anterior | Ver fotos instantáneas | Siguiente > |
|
|




