CineTres mil millones de pares de bases por célula |
Compre ahoraDe La biología del desarrollo prenatal |
Guión: Ọkọọkan ninu awọn ẹyin keekeke ti a fi da enia ni o ni ọkẹ aimoye awọn ohun ti a darukọ loke wọnyi ninu. DNA inu ọkan ninu awọn ẹyin keekeke ti a fi da enia yi ni oriS̩iriS̩i alaye ninu, ti o jẹ wipe, bi a ba fẹ kọ wọn silẹ ni ọrọ, lẹta ekini ninu ọkọọkan awọn ohun ti a darukọ wọnyi yio gba oju ewe iwe ti o to miliọnu kan ati aabọ! Bi a ba gbe wọn si ẹgbẹ ara wọn, DNA inu okansoso ninu awọn ẹyin keekeke wọnyi yio gun to iwọn ẹsẹ mẹta ati diẹ tabi mita kan. |
Todas las edades en referencia a la fecundación, no al último período menstrual.
|
< Anterior | Ver fotos instantáneas | Siguiente > |