CineEl período embrionario |
Compre ahoraDe La biología del desarrollo prenatal |
Guión: Ni ọsẹ mẹjọ ekini lẹhin idapọ ẹyin ọkunrin ati obirin, ọmọ enia ti i ndagbasoke ninu ni a npe ni ẹmubirayoo, eyiti o tumọ si “idagbasoke ninu." Akoko yi, ti a npe ni akoko ẹmubirayoo, ma nfarahan nipa fifi awọn orisirisi ẹya-ara le lẹ. |
Todas las edades en referencia a la fecundación, no al último período menstrual.
|
< Anterior | Ver fotos instantáneas | Siguiente > |