CineEl corazón en acción |
| Compre ahoraDe La biología del desarrollo prenatal |
|
Guión: Ọkan enia ma nmi niwọn igba mẹtalelaadọfa laarin isẹju kan. Sakiyesi bi awọ ara ọkan naa ti nyipada bi ẹjẹ ti nwọ inu awọn iho rẹ, ti o si njade. Ọkan enia maa nmi niwọn igba mẹrinlelaadọta miliọnu ki a to bi ni, ati niwọn igba miliọnu mẹta, o le diẹ ni igbesi aye enia ti o pe ọmọ ọgọrin ọdun. |
|
Todas las edades en referencia a la fecundación, no al último período menstrual.
|
| < Anterior | Ver fotos instantáneas | Siguiente > |
|
|




