CineADN |
Compre ahoraDe La biología del desarrollo prenatal |
Guión: Awọn eroja mẹrindinlaadọta ti o wa ninu saigọọti duro fun ekini ninu awọn alailẹgbẹ eto igbesi aye ọmọ enia titun. Eto pataki yi wa ninu awọn ohun kan ninu agọ ara ti a npe ni DNA. Ninu wọn ni asẹ fun idagbasoke gbogbo ara enia wa. Awọn ohun ti a npe ni DNA yi farajọ akaba ti o lọ pọ, ti a npe ni dọbulu hẹlikisi. Lara akasọ ara akaba naa ni awọn ohun kan, ti a npe ni guanini, sitosini, adinini, ati taamini wa. Guanini yi le darapọ mọ sitosini nikan, adinini si le darapọ mọ taamini. |
Todas las edades en referencia a la fecundación, no al último período menstrual.
|
< Anterior | Ver fotos instantáneas | Siguiente > |