Skip Navigation

Cine

La mórula y el blastocisto


 

5 días

Compre ahoraDe La biología del desarrollo prenatal

Guión: Laarin ọjọ mẹta si mẹrin lẹhin idapọ ẹyin ọkunrin ati obirin, ẹyin naa yio maa pin si ọna pupọ, wọn a ri rogodo, a si npe oyun inu naa nisisiyi ni morula.

Laarin ọjọ mẹrin si marun, iho kan yio waye laarin awọn ẹyin rogodo wọnyi, a si npe oyun inu naa nisisiyi ni bilasitosisiti.

Awọn ẹyin keekeke ti o wa ninu bilasitosisiti yi ni a npe ni akojọpọ ẹyin ti inu, eyiti yio ko ara wọn jọ pọ lati di ori, ara, ati awọn ẹya ara miran ti o S̩e pataki fun idagbasoke ọmọ enia.

Todas las edades en referencia a la fecundación, no al último período menstrual.
 <  Anterior    Ver fotos instantáneas    Siguiente  > 
La mórula y el blastocisto
La mórula y el blastocisto
Tres mil millones de pares de bases por célula
Tres mil millones de pares de bases por célula
Amnios y capas germinales
Amnios y capas germinales
Desarrollo embrionario temprano
Desarrollo embrionario temprano
Desarrollo humano
Desarrollo humano
Corazón y sistema circulatorio
Corazón y sistema circulatorio
Previous Set Previous Picture Next Set Next Picture