Skip Navigation

Cine

Sentido del olfato


 

6 meses, 2 semanas

Compre ahoraDe La biología del desarrollo prenatal

Guión: Ohun gbogbo ti o wulo fun gbigb’oorun nkan ti bẹrẹ sii S̩iS̩ẹ. Ẹkọ lori awọn ọmọ ti osu wọn ko pe S̩e akiyesi agbara ati gbọ oorun lati bi ọsẹ kẹrindinlọgbọn lẹhin idapọ ẹyin.

Bi a ba fi ohun ti o ladun sinu omira apo ile-ọmọ, ọmọ naa yio ma gbe itọ mi ju bi o ti yẹ lọ. Sugbọn ọmọ inu oyun kii gbe itọ mi to bi o ti yẹ bi a ba fi ohun ti o koro sinu omira. Ọmọ naa yio fun oju rẹ pọ lẹhin naa.

Todas las edades en referencia a la fecundación, no al último período menstrual. Un mes = 4 semanas.
 <  Anterior    Ver fotos instantáneas    Siguiente  > 
Sentido del olfato
Sentido del olfato
Respuesta a la luz
Respuesta a la luz
Ecografía en 4D
Ecografía en 4D
Ecografía en 4D
Ecografía en 4D
Ecografía en 4D
Ecografía en 4D
El feto parece estar menos arrugado
El feto parece estar menos arrugado
Previous Set Previous Picture Next Set Next Picture