Skip Navigation

Cine

El plegamiento del embrión


 

3 semanas

Compre ahoraDe La biología del desarrollo prenatal

Guión: Larin ọsẹ mẹta si mẹrin, awọn eto ẹya ara yio yanju, gẹgẹbi ọpọlọ, ọpa-ẹhin, ati ọkan ọmọ inu oyun naa, eyiti a le fi irọrun damọ lati ẹgbẹ apo ẹyin.

Idagbasoke yi ma nmu ki oyun inu ti o ti S̩e pẹrẹsẹ tẹlẹ ri ki o sẹpo. Ilana yi a maa so lara apo ẹyin pọ mọ awọ ti a fi tẹ inu ẹya ara ti ngbe ounjẹ kaakiri ara enia, wọn yio si di aya ati inu ikun ọmọ inu oyun ti ndagba naa.

ỌSẸ MẸRIN

Todas las edades en referencia a la fecundación, no al último período menstrual.
 <  Anterior    Ver fotos instantáneas    Siguiente  > 
El plegamiento del embrión
El plegamiento del embrión
El plegamiento del embrión
El plegamiento del embrión
Desarrollo del corazón
Desarrollo del corazón
El embrión y el saco vitelino
El embrión y el saco vitelino
Desarrollo embrionario
Desarrollo embrionario
Secciones del cerebro
Secciones del cerebro
Previous Set Previous Picture Next Set Next Picture